IRIN OMI MI
Ṣe ό leè ya àwὸrán ohun ti ό lérὸ?
Nígbàti àwọn ọmọ rẹ bá lọ pọn omi, ní ipadàbọ wọn sọ fún wọn pé ki wọ́n ya àwὸrán ohun ti wọ́n ri, ohun ti wọ́n gbόὸόrùn, ohun ti wọ́n gbọ́, ohun ti wọ́n fi ọwọ́ kàn àti ohun ti wọn tọ́wὸ.
Wọ́n leè ṣe ìwé-iránti ojoojύmọ́ ti àwọn ìrìn omi wọn, tàbi ṣe ìgbàsílẹ̀ àwὸṣe wa níbi: