E KU ABO SORÍ ÌKA NNI OWO EYO MARUN UN!

Nítorí náà kiní gbogbo wa jẹ́?

A wa níbí láti ṣe àtilẹyin fún Ọ láti tan imọ́lẹ̀ ti o dára jùlọ si ọjọ iwájú re.

Àti pé èyi ni bíi….

Àwọn ọgbọ́n wo ní o nílὸ láti jẹ́ ὸbi aláádùn àti alṣeyọrí, olùkọ́, àgbẹ̀, onísirὸ, onímọ̀-ìjìnlẹ̀, onímọ̀-ẹ̀rọ, olùdarí fíìmù, onímọ̀ àyíká, ὸǹkọ̀wé?

Eyi yόὸ gba IRONÚJINLẸ̀ IFỌ̀RỌ̀WÉRỌ̀ IBÁNÍSỌ̀RỌ̀PỌ̀ ÀTINÚDÁ.

Àti irú ènìyàn wo ní ìwọ yόὸ fẹ́ láti jẹ́?

Ṣe ìwọ fẹ́ láti faramọ́ ASA rẹ láti ní ABόJUTό, Ibáraẹnísọ̀rọ̀ ki o sí wà ni ISỌPỌ pẹ̀lú AGBEGBE rẹ?

Fojú inú wὸό pé o jẹ́ ayàwὸrán àti pé àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí jẹ́ àwọn àwọ̀ lόrí páléti rẹ. . Ìwọ yόὸ da àwọn ọ̀rọ̀ náà pọ̀, ṣe àyẹ̀wὸ àti ìdánrawὸ pẹ̀lú wọn, k àwọn ọgbọ́n tuntun ki o si sẹ̀dá nǹkan ti ό dàbi aláìlẹ́gbẹ́ sí ọ.

Gbogbo àwọn iṣẹ́ wa leè ṣeéṣe yálà lẹ́níkan tàbi pẹ̀lú ẹbí rẹ àti àwọn ọ̀rẹ́. Wọ́n jẹ́ ohun igbádùn fún gbogbo àwọn ènìyàn láìka ọjọ́-orí!

Kὸ sí ọ̀nà ti o tọ́ tàbi ọ̀nà ti kὸ tọ́ láti ṣe àwọn iṣẹ́ wa. Mú tàbi ki o yan àwọn ti o fẹ́ràn jùlọ, o leè bẹ̀rẹ̀ èyikéèyi iṣẹ́ níbikibi àti nígbàkúùgbà.

Ní ÌKANNI OWO EYO Márùn ύn a ní ὸfin kan:

JE IGBÁDÙN!

BAWO NI O SE LEE SẸ̀DÁ OHUN KAN?

Njẹ́ o jẹ́ ẹni ti o ni ẹ̀mi AJUMOSE, SISEWADII, IBAWI, ERO INU, àti ITERAMOSE? Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbogbo láìka ọjọ́-orí leè bi ara wọn ní àwọn ibéèrè wọ̀nyí.

.O leè ṣe kẹ̀kẹ́ tirẹ fún ara rẹ gẹ́gẹ́ bi olùtọ́jú tàbi olùkọ́ní àti láti ṣe ohun ti ό rọrùn fún àwọn ọmọdé ní agbègbè rẹ.

Se kikùn àwọ̀ nínú apákan ti àarin ti ό dára jùlọ èyi ti o leè dúrό fún àwọn agbára isẹ̀dá rẹ.  ipèlé mélὸό ní ìwọ yόὸṣe kikùn ní àwọ̀? Agbára rẹ yόὸ máa dàgbà ní si bẹ̀rẹ̀ láti àarin kẹ̀kẹ́.

ṢE AKỌSÍLẸ̀ RẸ!

Kiní o ṣe ọ ní itají? ?Kíni o ti rí, ti o fi ọwọ́ kàn, ti o ti gbọ́, ti o ti gbὁὸὁrùn tàbi ti o tọ́wὸ ti ό jẹ́ iyàlẹ́nu?

Wo ὸké, wo ní àyíká rẹ, ki o si gbé ihùwà ṣíṣe akọsílẹ̀ rẹ̀ wọ̀.. O leè ṣe èyi pẹ̀lú iyàwὸran tàbi kikọ, tàbi àwọn méèèji. Gbogbo àwọn ayàwὸran, onímọ̀ iìjìnlẹ̀ sáyẹ́nsí, dὁkità ni wọ́n nṣe àkiyèsi, àyẹ̀wὸ, béèrè àwọn ibéèrè, ti wọ́n si nwa àwọn idáhùn to ni ojútùú isẹ̀dá.

Njẹ́ o ṣetán?

E JEKA LO !