ÀWỌN KAADI LẸ́TA

Gbogbo ẹbí leè je ìgbádùn ṣíṣe àwọn ohun èlὸ ẹ̀kọ́.

Gé àwọn lẹ́tà láti inu aṣọ ki o lẹẹ́ pọmọ́ àwọn lẹ́tà sí àwọn ègé kékeré ti pẹpẹ tàbi itítẹnu. Lẹ àwọn aṣọ náà pọ láti isàlẹ̀ ki ọmọ ilé-ìwé leè mọ ọ̀nà ti lẹ́tà náà nlọ.

 àwọn lẹ́tà kékeré àti àwọn lẹ́tà nlá.

Àwọn ọmọ ilé-ìwé kékeré púpọ̀ leè ṣe àlàwẹ́ si-méji àwọn lẹ́tà náà ki wọn si wá àwọn lẹ́tà náà pẹ̀lú ìka wọn.

Copyright Polly Alakija