ÀWỌN AWὸRAN

Ní ọdún díẹ séyìn,a ún lo àwọn ẹranko nínú àwòrán láti ṣe ìrànlọwọ jíjé isé. Tí ẹnìkan bá ní àwòrán kìnìún tàbí ti rhinoceros (àgbánréré) ní ilé wọn kíni eléyi sọ nípa wọn ? Tí ẹnìkan bá ní àwòrán eku tàbí aran kan kíni eléyì sọ nípa wọn?

Ní Ọrundún kọkànlélógún, ọpọlọpọ àwọn ẹranko ní ó wà nínú ewu. A n se àfihàn nípasè àwòrán tí àwon olùyàwòrán tí ó nse ètò ìdábòbò àyíká n yà.Wọn jẹ aṣojú ní àwòrán nípasẹ àwọn oṣere ti o ṣe iṣeduro latí daabobo ayika.

Copyright Benin Art

Àwọn àmọtẹkùn idẹ tí Ọrundún kẹrìndínlógún láti Bènín , Nígeria.  Àmọtẹkùn idẹ bíi èyí ni wón fi só ẹnu-ọnà ilé ọba Obà.

Copyright Jose Rodriguez

Adá ide(ìlẹkẹ) ìbílè Yorùbá ti ogún Ọrundún. Àwọn ìlẹkẹ gílásì jẹ iyebíye púpọ. Kíni o rò pé erin atí eye idì dúró fún?

Copright falko1 Graffiti

Àwòrán ara ogírí nípasẹ CALDER ní Cape Town, South Africa. Paapaa ilé kékeré le jẹ kanfasi fún ẹranko nlá jùlọ !

Copyright William Kentridge, South Africa 2019

“ Rhinocerous ” nípasẹ William Kentridge , South Africa 2019. Rhinocerous (àgbánréré) jẹ ẹranko líle atí ẹranko ìgbẹ. Kíni ìdí tí o fi rò pé olùyàwòrán fi ya abọ oúnjẹ ní ẹnu rẹ?

Copyright Cai Guo-Qiang

“Àjogúnbá (Heritage)” nípasẹ Cai Guo- Qiang, Australia 2013. Àwọn ẹranko atí ènìyàn bákanna nílò ìráyè sí omi mímọ.

Copyright Polly Alakija

“Bellyful” Ya akèngbè omi 2019, Ìjèbú, Nígeria

Ẹranko wo ní ìwọ yoo yàn láti ṣe aṣojú ẹni tí o jẹ? Báwo ní ìwọ yoo ṣe àfiwé àwòrán ẹranko yii? Ṣé o ṣetán láti ya àwòrán, kíkùn àti fífín ère? Jẹ kí á lọ!