BÀ AJÀFẸTỌ ỌMỌ ÈNÌYÀN PÀDÉ
Vanessa Natake

Copyright Vanessa Nakate

Èyí ní Vanessa.

Vanessa ní a bí ní Uganda ní ọdún 1996. O di ajàfẹto ènìyàn ní orilẹ-èdè rẹ nítorí aifọkanbalẹ oru to mu atí airọjo. Ní ibere ohún nikán ní ajàfẹtọ ní ìta ẹnu ibodè tí Ilé-ìgbìmọ aṣòfin ti Uganda ṣùgbọn laìpẹ ó ti ṣè ìwúrí ìgbìyànjú fún àwọn ọdọ ti ó pe ara wọn ní “Ọdọ fún Áfíríka Ọla”.

Forest
Copyright J. van der Ploeg/CIFOR
plantaciones-S-E-Africa-APAISADA
Copyright GAZETECIYUSUFYAVUZ

Àwọn igbó Congo ti wà ní ìparun. Kíni ìwọ yóò ṣe látifi ṣe ìrànlọwọ láti dáábò bo ọjọ iwájú ayé?

Ọdọ fún ọjọ iwájú Áfíríka ti se agbẹjọro láti dáábò bo àwọn igbó nlá ti Congo. Kii ṣe àwọn agbalagba níkan ní o le ṣe iyatọ: Iwo naa le ṣe ayipada nkan! Níbayi Vanessa ba àwọn oludari Orile-ede kakiri agbaye sọrọ.

Copyright Simon Dawson/Bloomberg
Copyright AaravSeth

Kíni o fẹ yipadà? Njẹ o lè ṣe àpẹrẹ sara posità lati sọ ọrọ fún àwọn elédè miran/ alaigbédè tirẹ?

Ṣe igbasilẹ ki o si Ṣe !

Five Cowries