BÁ ELÉWÌ PÀDÉ
Chuma Nwokolo

Copyright Imagine Nations

Èyí ní Chuma

Chuma Nwokolo jẹ ònkọwé àti eléwì ní orilẹ-ede Naijiria. Ó kọwé nípa àwọn ọràn tí ó kan gbogbo ènìyàn ní àgbáyé. Chuma Nwokolo wà ní aìfonkàn balẹ pẹlú ọpọlọpọ nkan pẹlú ìwúlò láti dáábò bo àyíká naa.

Ṣé o rò pé ewì kan gbọdọ wà nínú ìwé kan?

Copyright Polly Alakija

Èyí ní ewì kan tí Chuma Nwokolo ké tí a yà sará ọkọ nlá kan. À ún lo ọkọ nlá yìí látifi kó igi nínú igbó.

Gbé pẹlú àwọn igi loní

gbé laàrin àwọn ẹyà kan

Ẹnití nkánjú

Tí ó jẹ òdòdó tí ó tanná

Ẹnití ìfojúsùn / ìlépa rẹ jẹ ọrun

Kíni o n lepa?

Copyright Polly Alakija