BẸRẸ GÍGÉ!
Dojúkọ mí kín dojúkọ ẹ́ Ge àwọn ita

O le sọ púpọ nípa ẹranko, nípa wíwo profaili wọn.

Copyright Getty Images

Kíni ìdí tí àwọn erin fi ní irú ògbólògbó ìwo imú bẹ?

Copyright Omar Bariffi

Kíni ìdí tí àwọn ògòngò fi ní àwọn àgógó nlá?

Copyright Pinterest

Kíni ìdí tí ẹja erinmilókun fi ní irú ẹnu nlá bẹ?

Jẹ kí á ṣe gígé jáde kọjú sí mi kín kọjọ sí ọ to dọgba.

MSOW_3_Cut_Outs_2 (1)

O le fojú inú wo àwọn ẹda tuntun, kí o ronú bí wọn yóò ṣe dáàbò bò ara wọn.

Copyright Polly Alakija