BẸRẸ GÍGÉ!
Ìtì ẹiyẹ Penguiní
BẸẸNÍ Áfíríka ní àwọn penguuin! Púpọ àwọn ẹyà penguuin ún gbé ní Antarctica ṣùgbọn Áfíríka ní àwọn penguiní tirẹ.

Àwọn penguinní Áfíríka ma wàpọ títí ìgbésí ayé wọn àti nígbà gbogbo wọn ma padà sí ibi kanna ní South Africa àti Namibia ní ọdún kọọkan láti ṣe ìtẹ wọn. Àwọn penguins Áfíríka wà ní ewu. Ibùgbé wọn jẹ aláìmọ tí àìmọ sìn pọ si àti nítorí ìpẹja fún ìṣòwò kò sí ẹja tí ó tó fún wọn nínu òkun láti jẹ.
Àwọn penguins Áfíríka le bẹ somi ìwọn mítà ọgọfà labẹ omi láti pa ẹja.

Jẹ kí á ṣe ọpọlọpọ ìtì Penguins.
O nílò ìwé, ìkọwé, ege àti teepu.
Jẹ kí á lọ!




Copyright Polly Alakija