BẸRẸ GÍGÉ!
Jọwọ se Ìdáàbò bò!

Erin jẹ àmì àwọn ọlọpa Nígeria. Kíni ìdí tí o fi rò pé èyí se jẹ bẹ?

Copyright Nigeria Police

O rí àwọn erin tí ó jẹ aṣoju ní ara àwòrán ìlẹkẹ ìbílẹ, ní tí ère gbígbẹ, àti nígbà míràn lórí àwọn ilé àtijọ. Erin dúró fún agbára àti okun.

Copright Bamilleke Mask, Cameroon

Bamileke Elephant Mask from Cameroon.

Naijiria ti fi ìgbàkan ní àwọn erin tí ó tóbi jùlọ ní àgbáyè. Nísisìyí, nítori pípa wọn àti ìparun ibùgbé wọn díẹ nínú wọn ló kù.

Copyright ROA

Olùyàwòrán àdúgbò ROA ya muralli àwọn ẹranko tí ó wà nínú ewu sórí àwọn ilé kákàkiri gbogbo àgbáyé

Njẹ o mọ pé erin muu ìwọn omi tó bíi igba líta (200 litres) ní ọjọ kan? Ìyẹn jẹ ọgọrún(100) ìsin omi tí o mu!
Àwọn ọdẹ n pa àwọn erin kí wọn lè gba àwọn ìwo bíi ẹyẹ olówó iyebíye.

À ún pa àwọn Pangolins torí pé díẹ nínú àwọn ènìyàn ní ìgbàgbọ èké pé òògùn ti a bá fí ìpẹ́pẹ́ ara wọn se lè jẹ kí wọn ní àgbára.

Copyright ROA
Copyright ROA

Àwọn pangolins kákàkiri Áfíríka wà lábẹ ewu. ROA ti ya àwọn pangolins sí South Africa àti Gambia.

Copyright David Shepherd

Láti dáàbò bò ara wọn kúrò lọwọ àwọn apanírun àwọn pangolinní máa yí ara wọn sí bọọlu.

Download and Do!

Five Cowries

O lè ṣe ìgbàsílẹ kí o sì gé pangolin tirẹ.

O lè ṣe ìgbàsílẹ kí o sì gé erin tirẹ.

Copyright Polly Alakija