Ẹ JẸ KÍ Á KUN ÒDÀ
Àwọn Múrálì Ìyàlẹnu
Erinmi tóbi ó sì lágbára. Erin ní àwọn ìwo nlá. Àwọn Ìjàpá ní ìkarahun tó le gidi. Láíbìkítà àwọn nkan wọnyí àwọn ẹda lè ní ìpalára.

“Turtle and Crocodile” nípasẹ ROA. Queensland Australia
Ṣé o lè fojú inú wo erin tí àwọ rẹ jẹ asọ Ànkárá?
Njẹ o lè fojú inú wo òoni tí eyín rẹ rọò?
Njẹ o le lè fojú inú wo ìjàpá tí a ṣèdá láti inú irun-òwú?

“Sọnù” nípasẹ Louis Masai.
Gbogbo wa nífẹ àwọn ẹranko.
Àwọn olùyàwòrán kákìrii ayé fẹràn wọn paapaa wọn sì wà ní ìbèrùbojo pé àwọn ẹdá ẹranko díẹ sìi lè parẹ láìpẹ.


Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !
Copyright Polly Alakija