Ẹ JẸ KÍ Á KUN ÒDÀ
Igbó Muralli tó Gbayì

Nígbà kan, níbiti a ti ní àwọn ìlúnla ti o ní olugbe miliọnu ènìyàn, a ní àwọn igbó irà àti àwọn ọnà omi tí ó jẹ ilé fún àwọn miliọnù oríṣriṣi èdá.

Kíni o rò pé ó wà ní ibí tí ilé rẹ w báyí ?
Ṣé igbo ló wà níbè?
Ṣé odò ló wà níbè?

Copyright Gauri Waikar
Copyright https://foursquare.com

Díẹ nínú àwọn olùyàwòrán àdúgbò fẹràn láti fojú inú wo ohun tí ó wà ní ipò àwọn ilé wònyí.

Copyright Pinterest

Iṣẹ ọna ìta nlá bẹrẹ pẹlú ìmọràn nlá àti àpẹrẹ nlá kan.

Copyright Polly Alakija

Ó kàn ọ! Ṣe ìgbàsílẹ àwọn àwòrán ilé wọnyí kí o bẹrẹ isẹ síse!

Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !

Five Cowries

Copyright Polly Alakija