Ẹ JẸ KÍ Á KUN ÒDÀ
Insect Keleidoscope
Christopher Marley jẹ olùyàwòrán láti Ìlú Amẹrika. Ó rin ìrìn-àjò káàkiri àgbáyé ón wá àwọn ohun èlò láti ṣiṣẹ pẹlú.
Ó ṣẹdá àwọn àṣà ẹlẹwà tí ó ṣe ayẹiyẹ ẹwà ti ẹranko àti kòkòrò. Ó nlo iṣẹ rẹ láti dúró fún àbò ìsèdá agbègbè.

“Elegans Prism”
A gbékẹlé àwọn kòkòrò láti tọjú ìwọn túnwọnsì nínú ìsedá. Ogójì ìdá ọọgọrun àwọn irú kòkòrò wà lábẹ ewu. Kíni gbogbo àwọn ẹranko, eye àti eja yóò jẹ?

“Aesthetica#1”
Ọpọlọpọ àwọn kòkòrò yé ẹyin wọn sínú omi. Àwọn ẹyin wọnyí ún pèsè ounjẹ fún ọpọlọpọ ẹja.

Àwọn ìdin ẹfòn .

Lamilami tó yé ẹyin .
Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !