Ẹ JẸ KÍ Á KUN ÒDÀ
Joseph Cartoon wá láti Kenya

Josefu fẹran àwọn ìlànà.
Nígbà kan ó dàbí pé àwọn ẹranko àti ènìyàn fí ara pamọ sínú àwọn àwòrán, wọn nira láti rí nígbà míràn.

Copyright Jospeh Cartoon
Copyright Jospeh Cartoon

Nígbàmí àwọn olùyàwòrán kí fún àwọn àkọlé iṣẹ wọn lórúkọ. Àwọn àwòrán méjì wọnyí jẹ “aláìlákọlé”. Kíni àkolé tí ó fún wọn?

Ọpọlọpọ àwọn ẹiyẹ àti àwọn ẹja má farapamó, ó sì sòro púpò láti rí wọn. Èyí jẹ ọnà kan tí wọn fi ún dáàbò bò ara wọn. Níbáyìí tí ọpọlọpọ ènìyàn wà lórí ilé ayé, àyè díè ló wà fún àwọn ẹranko, fún ìdí èyí aní láti dáàbò bò wọn

Copyright Kate Mcalpine, University of Michigan
Copyright Tane Sinclair-Taylor,

Díẹ nínú àwọn ẹranko àti ẹja paapaa lè yípadà bí wọn ṣe má ún rùn kí wọn le dáàbò bò ara wọn. Àwọn ẹja wọnyí dàbí iyùn tó wà láyiká wọn, wọn le yí òórùn wọn padà láti ma rùn bi àwọn iyùn àyíká wọn.

Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !

Five Cowries
Copyright Polly Alakija

Èyí ní àwọn àwòrán méjì tí Josephs fún ọ láti kùn wọn. O lè ṣàfikún àwọn ìlànà tìrẹ. Ṣé ìwọ yóò fún àwọn ẹranko rẹ àti ẹja rẹ ní ifarapamọ?