GBÉ ÀWỌN ỌDÀ JÁDE
Ablade Glover

Ablade Glover jẹ olùyàwòrán láti Ìlú Ghana.
O ní aṣa aláìlẹgbẹ nítorí naa ó rọrùn láti dá iṣẹ rẹ mọ.

Copyright Ablade Glover

“Ní Gbogbo Ọna” 2014

Copyright Ablade Glover

“Àwọn Oju Pupa” 2014

Nígbàtí o bá wòó ní pẹkípẹkí àwọn isẹ ọwọ rẹ dàbí àwọn àpẹrẹ ṣùgbọn nígbàtí o bá dúró sẹhìn o lè ríi ọpọ ènìyàn àti àwọn ọjà tí ó kún.

O lè yaa àwòrán bí eléyìí paapàá!

Copyright Ablade Glover

Maṣe ṣọra kẹra, àyè wà fún ìdọtí àti ìgbádùn díẹ !