IṢẸ SÍSE TÓ RORÙN NÍ ÌṢẸJÚ MÁRÙN-UN
Dojúko mí kín kojú sí ọ
Nígbà mí a má n kọjú sí ara wa nítorí a nífẹ ara wa.

Nígbà mí a ní láti dojúkọ ara wa nítorí kò sí àyè láti wo ibò míràn!



O to àkókò láti se o wun tó rorùn!
Wàá nílò àwọn ìkọwé méjì, ọkán fún ọwọ kọọkan àti ìwé díẹ.
Àkókò fún ara rẹ.
Fún ara rẹ ní ìṣẹjú márun.
Àwọn ọwọ méjééjì gbọdọ má ya àwòrán ní àkókò kanná bí ọkọọkan.
Ya prófáílì ojú kan. O lè jẹ ìwọ , ọrẹ tó dára jùlọ tàbí ẹranko èyíkèyí.



Njẹ àwọn ojú rẹ n wo ara wọn nítorí wọn fẹràn ara wọn tàbí nítorí wọn kò ní àyànfẹ?!