IṢẸ SÍSE TÓ RORÙN NÍ ÌṢẸJÚ MÁRÙN-UN
Ẹranko dídá pọ mọ ra wọn!

Ní ogójì (40) ọdún sẹhìn a ti pàdánù ìdajì àwọn ẹyà tí ó ngbé inú omi. Gbogbo èyà ti dàgbà lórí mílíọnù ọdún. Wọn jẹ nkan arẹwa àti ìyanu àti nígbà mí nkan àjèjì!

Copyright theguardian.com

Ìjàpá inú omi

Polar wide
Copyright Tim Flach

òfàfà

whale-shark-swimming
Copyright Creative Common

Shark Whale

Kíni a lè ṣe láti dáábò bò àwọn èyà ewu ìparun wọnyí? Ó nira láti ronú ìyanu àti àjèjì tí díẹ nínú àwọn ẹranko jẹ.

Mú ère àdàpọ ẹranko tó rorùn yìí láti ṣẹdá àwọn ẹdá tuntun. Bẹrẹ pẹlú àwọn ẹdá mẹta, ge wón sí mẹta, àwọn ẹdá oríṣiríṣi mélo ní o lè ṣẹdá láti inú rẹ?

Copyright Pollly Alakija