IGUN AKÉWÌ
Kékeré pọ
Nígbà míràn ó lè ṣe/ṣa ipá díẹ sii nípa sísọ kékeré. Akéwì Chuma Nwokolo nígbàkan lo àwọn ọrọ díẹ.
ÌPARUN
On Faore Island (Ló rí Erékùṣù Faore)
Ní Abúlé Muli wà
Tí kò ní ènìyàn kankan.
nípasẹ Chuma Nwokolo
Erékùṣù Faroe wà ní etíkun etí òkun Scotland.

Tí miliọnu ènìyàn bá wà lórí Erékùṣù Faroe báwo ní ewì yóò se rí nígbana?
Njẹ o le kọ ewì nípa ìparun?
Erékùṣù Èkó jẹ ibùgbé fún ẹfọ̀n omi àti àwọn ọ̀nì. Bayi o tí kún fún ile àti àwọn ọjà.
ÌPARUN
Ní Èkó
Erékùṣù kán wà
Láìsí ẹfòn omi.
nípasẹ Olumide
Ókàn ọ báyii!
