ÌWỌ NÁÀ LÈ SE
Àwọn àjèjì àti àwọn ìyanu
Àwọn ẹranko ti dàgbà sí láàrin miliọnu ọdún sẹyìn. Wọn ṣe àbà ara wọn ní àwọn ọnà oríṣiríṣi.
Ìfarapamọ ṣe ìrànlọwọ fún wọn láti sápamó kúrò lọwọ àwọn apẹranjẹ.



eja odo dragoni leléyi, ẹja osàn ti n fo àti ògà yìí ti ní ìbámu láti dàpọ mọ agbègbè wọn.
Jẹ kí á ṣẹdá díẹ nínú àwọn ẹdá aṣiwèrè tí ara wa.
Ìwọ yóò nílò:
Paali
Sisọsi
Àwọn ọpá
Oda ti o ba ní diẹ
1. Tí o bá ní ọdà, kun ìlànà sórí paali rẹ. Ronú nípa àwọn àbàwọn lára àmòtékùn kan, àwọn ìlà ara àbìlà, ìpẹ́pẹ́ ara ẹja. O tún leè fa àwọn ìlànà wọnyí síi.

2. Gé àwọn àpẹrẹ láti inú paali.

3. Gé àwọn ihò sí ara ẹgbẹ àwọn àpẹrẹ kí àwọn apẹrẹ le wo inú ara wọn.

4. Ṣe ojú àti etí, ìrù àti ìwo, kí o lo àwọn igi láti fi kún wọn láti jẹ kí ẹranko rẹ jẹ àjèjì!
Bayi pe o ti ṣe ẹda aṣiwere rẹ, orukọ wo ni iwọ yoo fun ni?