ÌWỌ NÁÀ LÈ SE
Ẹja Jelly!
Àwọn ẹja jelly tí wà ní àwọn òkun kákàkiri àgbáyé fún ọdún irinwó lé ọgọrùn mílíọnù. Àwọn ẹja jelly wà ṣááju àwọn dinososi. 95% marundinlọgọrun ìdá ọgọrun ara ẹja jelly jẹ omi !

Láarin miliọnu ọdún séyìn àwọn ẹja jelly kò ní láti dàgbàsókè púpọ. Wọn kò ní ẹdọfóró tàbí ọpọlọ wọn ko ní ẹjẹ paapàá. Wọn jẹ ẹyà tí o ṣaṣe yọrí púpọ gẹgẹ bíi wọn ti jẹ.

Jellyfish lè gán èyàn pèlú oró tó burú. Àwọn ẹyà ẹja Jelly ún pọ si púpọ nítorí ìyípadà afẹfẹ.

Àwọn àwòṣe ẹja jelly wọnyí rọrùn láti ṣe. Gbogbo ohun tí o nílò diẹ ní ike omi àti okùn.


Copyright Polly Alakija
Tí a kò bá ṣetọjú àyíká wa a ó ní àwọn okún tí ó kún fún ike omi àti ẹja jelly!