ÌWỌ NÁÀ LÈ SE
Jẹ́ agbẹ́ ère Sculptor
Ṣaájú kí àwọn agbẹ ère tó gbé ère tó tóbi, wón á kọkọ gbe kékeré iré rè kan ná.
Èyí ní a pè ní maquette.

Cheetah Maquette tó rìn
Dylan Lewis 2012

Ehoro jókòó lórí ògiri
Maquette kan Guy Du Toit
Ọpọlọpọ àwọn olùyàwòrán ti ní àtìlẹyìn nípasẹ William erinmi ẹní ọdún ẹgbẹrún mẹrin ará Egipti.

“William”
Tí o bá lè rí amọ ní agbègbè rẹ o lè ṣe èyí paapàá!
Bẹrẹ nípa dídáṣe díẹ nínú àwọn apẹẹrẹ ìpìlẹ. Bọọlu yíká, òbìrí, òkòtó.