KÓ GBOGBO RẸ SÍLẸ KÍ O SÌ YÀWÒRÁN
Àwọn Erinmi tó láyọ àti Àwọn apẹrẹ obírí miíràn
Ní Nígeria àwọn erinmi kékeré kan wà ṣùgbọn wọn ṣọwọn púpọ. Erinmi jẹ abálẹ se. ÈyÍ túmọ sí pé wọn má sùn lójúmọmọ wọn á sì má sisé ní alẹ. Kínìdí tí o fi rò pé wọn fí ṣe èyí?

“William” erinmi tí a ṣe ní ọdún (egbèrún mérin) 4,000 sẹhìn ní Egipti. Ó wà ní Ilé-ìṣọ nlánlá tí Ìlú nlá New York, AMẸRIKA.
Àwọn Kìnìún wà tẹlẹ ní gbogbo orílẹ-èdè Naijiria. Báyi kò jú bí ọgọọrún lọ to kù nínú wọn nítorí ibùgbé wọn wà nínú ewu.


Ṣé o ṣetán láti ya àwòrán? Pọn ìkọwé rẹ kí o jẹ kí a lọ! Àwọn apẹrẹ ìpìlẹ ọpọlọpọ nkan ni ó jẹ bi: iyika, obiri, àti okoto.


Copyright Polly Alakija
Rántí pé, Kíkọ́ ni mímọ̀!