KÓ GBOGBO RẸ SÍLẸ KÍ O SÌ YÀWÒRÁN
Farapamọ: Gbogbo Ìyípadà!

Ọpọlọpọ àwọn ẹiyẹ àti ẹja ní o wà nínú ewu nítorí ibùgbé wọn wà nínú ewu. Ìyípadà ojú-ọjọ n ṣẹlẹ ní kíakía. Àwọn ẹranko kò lè dàgbàsókè ní kíakía tó láti báamu.

Ònà kan tí ẹranko gbà dábòbo ara won ní nípasẹ fífarapamó kúrò lówó àwọn apẹranjẹ.

Copyright Jimmy White

Fojú inú wòó pé ò ngbé inú irà yìí, báwo ní Ìfarapamó rẹ yóò ṣe rí?

Copyright www.istockphoto.com

Fojú inú wòó pé ilé rẹ ní àwọn òdòdó wọnyí, báwo ní Ìfarapamó rẹ yóò ṣe rí?

Copyright indigoross

Fojú inú wòó pé ò ngbé lórí adágún-odò yìí báwo ní Ìfarapamó rẹ yóò ṣe rí?

Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !

Five Cowries
Copyright Polly Alakija

Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì ya àwọn ìlànà àbò Ìfarapamó fún ẹja eriminlókun tí o ní láti ṣe déédé sí àyè ti àwọn òdòdó, ọmọ tí ó dàgbàsókè láti dàbí àwọn ewé òdòdó lílì àti ewúrẹ tí ó wá àyè tuntun láti gbé nínú irà kan.

Copyright Polly Alakija

Ìlànà fún ẹja yìí láti dàgbàsókè àti láti ṣe dédé pẹlu ìgbé ayé titun rẹ nínú apẹrẹ tó kún fún ẹpà !