KÓ GBOGBO RẸ SÍLẸ KÍ O SÌ YÀWÒRÁN
Jẹ kí á so àwọn àmì pọ
Mo lánlá mo sì lágbára Ṣùgbọn mo nílò Ìdáábò bò!
Níbití a ti ní àwọn ìlú nlá ti àwọn ènìyàn ngbé “Dojúko Mí kín Dojúko” ibẹ ní igbó wà nígba kán, irà àti odò jẹ ilé fún orísìrísì ẹranko, ẹiyẹ àti ẹja. Báwo ní a ṣe lè dáábò bò wọn nígbàti wọn kò bá níbiti wọn yóò gbé mọ ?

Olùyàwòrán òpópónà SONNY ya àwọn ìtàn nípa àwọn ẹranko tí ó wà nínú ewu ní àwọn ìlú nla. Àwòrán ogírí ti àgbánréré Áfíríka wa ní Ìlú London ní U.K.
Kíni o rò pé o lè ṣe láti pàrọwà fún àwọn ènìyàn láti dáábò bò àwọn ẹranko ewu ìparun?

Olùyàwòrán òpópónà ROA, Bangkok, Thailand. Àwọn erin lágbára ṣùgbọn wọn nílò àtìlẹyìn àti àbò paapaa!
Ṣe Ìgbàsílẹ Kí o sì se !
Copyright Polly Alakija
So àwọn àmì pọ láti ṣe àwòrán bí ti ROA àti SONNY tìrẹ.
Kíni ìwo naa ó kùn ní ibití ò ngbé? Kíni ó nílò àbò ní agbègbè rẹ?