PÀDÉ OLÙYÀWÒRÁN
Dylan Lewis

Copyright Dylan Lewis

Èyí ní Dylan, Ó n ṣiṣẹ ní yàrá ìyàwòrán rẹ

Dylan Lewis jẹ olùfín ère láti South Africa. O nífẹ àwọn ẹranko.

Copyright Dylan Lewis
Copyright Dylan Lewis

Dylan Lewis lo iṣẹ-ọnà rẹ láti ṣe àíkiyèsí ìmòye tí ìwúlò láti dáábò bo àyíká àti àwọn ẹranko. Ó kọkọ ní ìwúrí ní nípasẹ àwọn àmọtẹkùn tí ó má rín kiri ní ìgbẹ jákèjádò ilẹ Áfíríka ṣùgbọn tí wón kò wọpọ mọ báyi .

Copyright Dylan Lewis
Copyright Dylan Lewis

Dylan Lewis kọkọ má n ṣe àwọn ère ní amọ na, lẹhìn na á fín wọn pẹlú idẹ. Idẹ jẹ àdàlú àwọn irin, èyí tí ó sábà má njẹ agolo àti cọppa. Èyí jẹ ìlànà tí àtijọ. Ní Nígeria àwọn alamọ tí n ṣe idẹ ní ohun tí ó jú egberun ọdún (1,000) lọ.

Copyright 2020 Adriaan Diedericks Studios
Copyright Benin Bronze
Copyright Benin Bronze

Àwòrán ẹkùn tí afi idẹ mọọ yí jẹ tí Bènín.