SETÁN FÚN A fíhàn
Múmi kálọ

Àwọn ẹranko wà ní ìbámu pẹlú àwọn agbègbè wọn .Níbí mílíọnù ọdún wọn tí dàgbàsókè. Àwọn ọrùn Àgùnfọn gùn látidé àwọn ewé titun lórí àwọn igi.

Copyright Julian Fennessy

Àwọn ìlà Àbìlà túmọ sí pé wọn ṣòro látiri nínú àwọn koríko gíga tí savannah.

Copyright Reuters/Goran Tomasevic, Kenya August 26, 2016.

Látiṣe àwọn puppets ìgbádùn wọnyí ìwọ yoo nílò:

1. Páálí

2. Okùn

3. Àwọn ìdérí ìgò

4. Straws

5. Ìlẹpọ àti òdà (tí o bá ní).

Copyright Polly Alkaija