SỌ ÌTÀN RẸ FÚN MI
Dòjé Ìtàn : Níbí àti Báyi

Níbo ní o wà ní báyi? Kíni o wà ní àyíká rẹ? Ṣe àpèjúwe ohun tí o rí.

Kíni o wà níbi, ní ọsẹ kan sẹyìn? Ní ọdún kan sẹyìn? àádóta ọdún sẹyìn? Igba ọdún sẹyìn? Njẹ ibi tí o wà nígbàgbogbo rí bí èyí? Tani o gbé níbí ṣáájú rẹ? Njẹ àwọn erin, àwọn ọni gbé níbí? Ṣe ibí yi ti jẹ ilẹ irà tàbí igbó tẹlẹ rí?

Copyright Deposit Photos

Omi ní o bó aṣálẹ Sàhárà nígbà kan rí .

Copyright Painting by Heinrich Barth ,1858

Timbuktu, Mali 1858

Kíni yóò wà níbí ní ọsẹ kan sí àsìkò yí ? Ní ọdún kan sí àsìkò yí ? Ní àádóta ọdún sí àsìkò yí ? Ní igba ọdún sí àsìkò yí ? Tani yóò gbé níbí lẹhìnná? Àti pé njẹ ibíyìíyóò dára sí níti ìlera àti ìgbádùn? Báwo ní O ṣe mú ibí dára sí?

Copyright Tim Laman

Níbití a ti ní àwọn ilẹ ìwapo àti àwọn ìlúnlá báyii ní àwọn irà àti àwọn ojú omi wà tẹlẹ.

Copyright blog.kugali.com

Ṣé báyi ní a òse ma gbé ní ọjọ iwájú?

1. Ya àwọn àwòrán onígun mẹrín sórí ìwé nlá kan.

2. Kọ ọdún kọọkan sórí àwọn àwòrán wòn yíi. O le lọ sẹhìn ní ti àtijọ àti sí ọjọ iwájú.

Story Board
Copyright Polly Alakija

3. Ṣe dòjé méjì, o le ló àwọn àwòṣe níbí.

4. Ya àwọn ẹranko sórí dòjé kan.

5. Ko ònnkà/nómbà sórí dòjé kejì.

Ṣe igbasilẹ àti O si se !

Five Cowries

6. Yi àwọn dòjé yíi lórí pátákó, kí o sì so ìtàn kan lórí ọdún tí dòjé rẹ sùn lé àti lórí ẹranko ti dòjé nàa gbé jáde. Nómbà / Ònnkà tí o wà lórí dòjé kejì yóò sọ fún ọ iye àwọn ẹranko látiní nínú ìtàn rẹ.

MSOW_3_Story_Dice_2
Copyright Polly Alakija