ÀWỌN AWὸRAN

Ǹjẹ́ omi rẹ mọ́ nítí gìdí? Èyí ni omi ẹ̀rọ tí a wὁ lábẹ́ máikírόsíkόὁpù.

Copyright Robert Owen Lehman Collection, Courtesy Museum of Fine Arts, Boston

Fiévet. Amì Idẹ Benin.

Nigeria circa 1750. Ilẹ̀ Nàìjíríà ní nǹkan bii 1750. Amì idẹ yìí jẹ ọ̀kan nínú àwọn tí o ju ẹgbẹ̀rún kan tí a fi ṣé ẹ̀yẹ Ilé-Ọba tí Isàkόso Benín.

Copyright Maurice Fiévet

Maurice Fiévet 1915–1997 láti orílẹ̀ èdè Faransé rin ìrìn àjὸ káàkiri Ilẹ̀ Afíríkà ό sì n ya àwὁran àwọn ènìyàn tí ό se alábàápàdé.

“Apẹja ni àwọn ènìyàn Niger Delta”

Copyright Joana Choumali

Joana Choumali wá láti Côte d’Ivoirẹ. O máa n ya fọ́tὸ ό sì máa n lo Iṣẹ́̀-ọnà láti sọ ìtàn. Nígbàtí ό bá lo ìlànà tí ό ju ọ̀kan lọ láti sọ ìtàn, èyí ni a n pè ní “mixed-media”.

“Kὸ sí láìnì ìparí”. 2019.

Copyright Victor Ekpuk

Victor Ekpuk wá láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. O nlo àwọn àmì Nsíbìdí àti Uli ayé àtíjọ tí Gúúsù ilà oὸrùn Nàìjíríà. Awọn àmì yìí tí wà láti ọgọọgọ́ọ̀rún ọdún.

“Itàn Apẹja Mìíràn”.

Copyright Samantha Reinders

Ní orílẹ̀ èdè Ghana, nígbàtí ẹníkan bá kú, wọ́n máa n se ayẹyẹ ìsìnkú rẹ̀ pẹ̀lú pόsí tό rẹwà tí ό sì ṣe àfihàn ohun tí ẹni náà ṣe lákὸόkὸ ìgbésí ayé rẹ̀.

Ewὁ nínú Iṣẹ́̀ ọnà wọ̀nyí ni o fẹ́ràn jù? Báyìí, kí ìwọ náà ṣẹ̀dá nkan Iṣẹ́̀-ọnà kan tí yὁὸ ṣe àpèjúwe “Bellyfull”.