DA OHUN GBOGBO SÍLE KÍ O YÀWORÁN
Imúwὁ Àlá

Bí o bá jẹ́ apẹja kíni ìwọ yὁὸ fẹ́ nínú imúwὁ àláà rẹ?

Jẹ́ kí a gbìyànjú yíyà àwọn àmì rόbόtό pẹ̀lú kọ́mpáàsì, kí a sí ya àwọ̀n ẹja.

Bi iwὁ kὸ bá ní kọ́mpáàsì, o leè ṣé ọ̀kan láti inú ìwé.

Kíkọ́ ni mímọ̀! Ya àwọn àmì rόbόtό ὸgidì pẹ̀lú kọ́mpáàsì rẹ.

Fi àwọn ìlà díẹ̀ kún un kí o leè di àwọ̀n ẹja!

Kíni iwὁ kὸ fẹ́ nínú àwọ̀n ẹja rẹ?

Kíni o n fẹ́ nínú àwọ̀n ẹja rẹ?

O tό àkόkὸ láti sẹ̀dá!

Báwo Imúwὁ Alá rẹ yὁὸ se rí?

Copyright Polly Alakija

Tèmi dàbí eléyìí!