DA OHUN GBOGBO SÍLE KÍ O YÀWORÁN
Jẹ́ kí a darapọ̀ pẹ̀lú àwọn àmì

Twins Seven Seven jẹ́ apákan ti ẹgbẹ́ àwọn oṣèré kan tí o n ṣiṣẹ́̀ ní ìlú Yorùbá tíse Oșogbo. Ìlú Oșogbo ní a mọ̀ pé o jẹ́ ilée Ayẹyẹ Oșun tí a tí n se Odún Oșun. Ajọdún náà jẹ́ ayẹyẹ ti odὸ àti agbára tí ẹ̀dá ní láti fún àwọn ènìyàn ní ohun jijẹ́.

Copyright Twin Seven Seven

“Olùfẹ́ Ẹja “1989
Ṣé o nífẹ̀ẹ́ ẹja? Bí o bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, o nílὸ láti dáàbὁ bo àwọn odὸ àtí àwọn ọ̀nà ojú omi kí o jẹ kí wọ́n wà ní mimọ́.

Copyright State of Osun Ministry of Innovation, Science and Technology

Àwọn ilẹ̀kùn un Grove Mimọ́ ní Oșogbo n ṣé ayẹyẹ Odò Ọṣun.

Wá ìkọ̀wé tὁ dára, dárapọ̀ pẹ̀lú àwọn àmì náà kí o ṣẹ̀dá àwὁrán Twins Seven Seven tìrẹ.

Five Cowries

Ṣe igbasilẹ ati Ṣe!

Copyright Polly Alakija