ÈYÍ NÍ ONÍSE ONA
Agostino Moreira de Melo

Copyright Polly Alakija

Agostino Morẹira de Melo wá láti orílẹ̀ èdè Brazil.

O nlo àwọn ohun tí o rí láti ṣẹ̀dá àwọn ohun tuntun to rẹwà.

Copyright Agostino Moreira de Melo
Copyright David Earle

Àwọn wọ̀nyí dàbí àwọn ὁké tí o nyí, ṣùgbọ́n a ṣẹ̀dá wọ́n láti ara àwọn ìdérí ike àti àwọn idẹrí ike àwọn àpὁtí. Ǹjẹ́ o tí yi ọ̀kan nínú àwọn wọ̀nyí rí? Bi o bá fe kí èyí ṣiṣẹ́̀, o ní láti ṣojúuṣé gẹ́gẹ́ bi ọlọgbọ́n!

Idábὁbὁ àyíká jẹ Agnostino lόgún púpọ̀. O nlo Iṣẹ́̀ ọnà rẹ̀ láti jẹ́ kí a ronú nípa irú ẹní ti a jẹ.

Copyright Rebeca Mojica jewelry
Copyright Agostino Moreira de Melo

“Mandala”

Mandala jẹ àpẹrẹ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé n lὸ gẹ́gẹ́ bi irànlọ́wọ́ láti leè ní ifọkànsín tό péye. Mandala máa n rí rόbόtό nígbágbogbo. Gbogbo àwọn Mandala n ní ààyè idojúkọ àarín.

Fojú inú wὁ ohun tí o leè ṣẹlẹ̀ nígbàtí ohunkan bá jábọ́ sínú omi kí o sì wὁ àwọn rírọ́ tí o n tàn káàkiri inú omi náà.

Èrὁǹgbà Agostino ni láti jẹ́ kí a kọ́ ẹ̀kọ́ láti máa fi ojú to yàtọ̀ wo àwọn nkan àti láti se ibéèrè lọ́wọ́ ara wa bόyá a jẹ́ ohun tí a fẹ́ láti jẹ́?

Copyright Agostino Moreira de Melo
Copyright Agostino Moreira de Melo