ÈYÍ NÍ ONÍSE ONA
Nnenna Okore

Nnenna nìyí.
Nnenna Okore jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àtí tí Ilẹ̀ Ọstrélià. Nnenna n lo àwọn ohun tí o rí ní àyiká rẹ̀ láti ṣe Iṣẹ́̀ onà rẹ̀ Nnenna Okore máa n lo àwọn ohun tí o rí ní àyiká rẹ̀ bí igi, koríko gbígbẹ àtí àwọn ewé.
Kíni àwọn iṣẹ rẹ̀ rán ọ létí?


“Aṣọ híhun àti àwọn iṣẹ́̀ mìíran”
Nígbàgbogbo Nnenna máa n wa àwọn nkan tí o leè lo láti Ṣé àwọn ohun iyanu. Àwọn okún àtíjọ, àwọn àgékù aṣọ, ike omi, igi àtí àwọn ewé gbígbẹ.


“Odi”
O sọ àwọn nkan ẹ̀gbin di àwọn iṣẹ́̀ ọnà ẹlẹ́wà. Nnenna máa n so nkan di ohun èlὸ ẹlẹ́wà tuntun nípa yiyà, kíkùn àtí hihun.


“Aki N’ukwa”
Àwọn nkan wo ní o wà ni àyíká rẹ tí o leè hun papọ̀? Ǹjẹ́ o leè hun odi àtí àwọ̀n tírẹ?