GBÁRADI FÚN ERE
Àwọn ọmọ́láńgidi ikùn ike

O rorùn púpọ̀ láti ṣe àwọ́n ọmọ́láńgidi wọ̀nyí!

Copyright Polly Alakija

Gbogbo ohun tí o nílὸ ní ike omi, sísọ́ọ̀sì, igi àti ìtàn láti sọ! O leè lo àwọn ọ̀rọ̀ inú “A Bellyful of Ideas” nínú ìtàn rẹ.

1. Da ojú ike rẹ kodὸ.

2. Fi sí orí igi.

3. Kùn tàbí ya ojú sí orí ike náà. Báyìí ní ise bẹ̀rẹ̀. Dájúdájú o leè ṣàfikún irun àtí àwọn filà àtí pé o leè kùn wọ́n pàápàá. Ríi dájú pé o lo àwọn ọ̀dà olόmi láti se kíkùn náà.

Copyright Wasiu Quadri