GBE AWON KÍKÙN JÁDE
Eja pípa
Kíni o fẹ́ kí o wà nínú àwọ̀n ẹja rẹ? Bí a kὸ bá ṣọ́ra, àwọn ike omi ní yὁὸ wọ inú àwọ̀n kìí ṣe ẹja, lẹ́yìn náà kíni a yὁὸ fi sínú ikùn wa?


Olorin Ghanian Kobina Nyarko fẹran ẹja.


Oníṣẹ́-ọnà ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Bridget Riley fẹ́ràn àpẹrẹ jiomẹ́tíríkì. Àwὁn iṣẹ́-ọnà kíkùn wọ̀nyí dàbí àwọ̀n ipẹja. Kíni yὁὸ ṣẹlẹ̀ bi àwọn àwὁrán kíkùn Kobina Nyarko bá bá àwọn àwὁrán Bridget Riley pàdé?


Abájáde leè dàbí eléyìí.