IWO NÁÀ LEE ṢÉE!
Awọn ìdérí Ike tὁ dára
Àwọn oníṣẹ́-ọnà káàkiri àgbáyé ń ṣé ìdánwὁ nípa lilo àwọn ohun élὁ tí a túnlὁ láti ṣe iṣẹ́̀ ọnà wọn.


Agostinho Moreira del Melo. Orílẹ̀ èdè Brazil
Se àkíyèsí àwọn ike omi tí a kùn ní oríṣiríṣi àwọ̀ àti àwọn ìdérí tí wọ́n wà ní títόbi lόríṣiríṣi.

Mary Ellen Croteau. Orílẹ̀ èdè Amẹríkà

Christie Beriston. Orílẹ̀ èdè Amẹríkà
O leè hun àwọn ìdérí ike rẹ pọ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ nípa lilo okùn tàbí wáyà.


Ijeoma Okoye


Copyright Judith Ezedimbu Ifunaya
Àwọn ọmọdé láti ìpínlẹ̀ Kaduna àti Ogùn, orílẹ̀ èdè Nàijiríà.