IWO NÁÀ LEE ṢÉE
Ọgbà Eja

Oníṣẹ́-ọnà Nnenna Okore n hun àwọn ère rẹ̀ pẹ̀lú lilo oríṣiríṣi àwọn ohun èlὸ.

Copyright Nnenna Okore

Igi àti àwọn ìwé ìrὸyìn àtíjọ ní a fi ṣe “Ọgbà”. IWO NÁÀ LEE ṢE ÈYÍ

O nílὸ igi díẹ̀, àwọn àpὸ ọ̀rá, ìwé ìrὸyìn àti okùn. Ge àwọn àpὸ ọ̀rá àtí ìwé sínú àwọn ìlà kí o sì hun wọ́n papọ̀ sí okùn.

Báyìí ni iṣẹ́ bẹ̀rẹ̀!

Copyright Polly Alakija