JẸ́ KÍ A SÍSE ONA KÍKÙN
Piet Grobler

Piet Grobler jẹ́ olùsọ̀tàn aláwὁrán ilẹ̀ South Afríca. O n sọ ìtàn nínú àwọn àwὁrán rẹ̀. Àwọn ẹranko ti Afiríkà jẹ́ orísun ìtàn àti ìmísí fún un.

Copyright Piet Grobler
Copyright Piet Grobler
Copyright Piet Grobler

Piet ya bi àwọn ẹranko ṣe ń ṣe, àti ìhùwàsí wọ́n, àti bí wọ́n ṣe rí. O leè sọ ohun tí àwọn ẹranko tí o wà nínú àwọn àwὁrán wọ̀nyí ń rὁ nípa wíwo àwọn ojú wọ́n. Bí àwọn ẹranko wọ̀nyí bá leè sọ̀rọ̀ kíni o rὁ pé wọn yὁὸ sọ?

Gbàsílẹ̀ kí o sì se 1 & 2

Five Cowries

Copyright Polly Alakija

Jẹ́ igbádun àwὁran kíkùn !

Sé o leè so ìtàn kan nípa ohun tí ὁ ń sele nínú àwọn àwὁrán wọ̀nyí?