JẸ́ KÍ A SÍSE ONA KÍKÙN
Twin Seven Seven
Twin Seven Seven 1944-2011, jẹ́ ọmọ Ibàdàn, Nàijiríà. O nífẹ̀ẹ́ àwὁran kíkùn, ìlù lílù àtí ijó jíjó.

“ Ọlọ́dẹ àti Agùnfọn”
Taani o rὁ pé ó wà ní ìṣàkóso níbí?

“Àwọn apẹja Alábùkúnfún”
Kíni o rὁ pé àwọn apẹja wọ̀nyí yὁὸ pa bí wọ́n bá siṣẹ́ ìpẹja lὁnìí?

“Àwọn Ọlọ́dẹ Ọ̀lẹ àti àwọn Ajìjàkadì Olὁrὁ, Aláńgbá, Iwin àti Sèbé”
Taani o ń jẹ ara wọn?
Nínú àwọn àwὁrán rẹ̀, Twin Seven Seven ń sọ àwọn ìtàn láti inú àṣà Yorùbá. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwὁrán rẹ̀ ń sọ ìtàn nípa bí ènìyàn àti ẹranko ṣé gbáralé ara wọn. O leè kun àwọn àwὁrán Twin Seven Seven ti ara rẹ. O leè ṣàfikún àwọn ìlànà tìrẹ.
Gbàsílẹ̀ kí o sì se 1 & 2
Copyright Polly Alakija