SỌ ÌTÀN RẸ FÚN MI
Àwọn ìtàn Scrabble

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn nkan ní o leè ṣé pẹ̀lú àwọn ìdérí ike. Bẹ̀rẹ̀ síi sà wọ́n jọ!

Gbá ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí ìdérí igo. Lilo ọ̀dà ilé tàbí èékánná láti kun àwọn lẹ́tà lόrí àwọn ìdérí ike. Nígbàtí o bá ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn lẹ́tà o leè bẹ̀rẹ̀ eré síse.

Ìwọ yὁὸ nílὸ:

  • Àwọn lẹ́tà ìdérí ike
  • Ọ̀rẹ́ kan

Gbìyànjú lẹ́nìkọ̀ọ̀kan láti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ bi ό ṣé leè pọ̀ to pẹ̀lú àwọ́n ìdérí ike náà. Fún ara rẹ ní gbèdéke àkόkὸ!

Copyright Ijeoma Okoye
Copyright Polly Alakija

Irú àwọn eré mìíran wo ni o leè se pẹ̀lú àwọ́n ìdérí ike?