ṢETÁN FÚN ERÉ
Bebi Ere Pelu Ika
Ókù sí ẹ lọ́wọ́! O lè máà ní ànfàní láti lọ sí tíátà ṣùgbọ́n o lè ṣe bèbíi eré tìrẹ. bayi.
1.Gé èwe-ìwé kéékèèké mẹ́wàá tí ó lè yí ìka rẹ ká.

2. Ya ojú sí ọ̀kọ̀ọ̀kan lára àwọn ìwé-ewé náà.

3. Wé ọ̀kọ̀ọ̀kan nínú àwọn bèbí náà mọ́ìka rẹ kọ̀ọ̀kan.

4. Àkókò eré dé! Eré mi dá lórí Rónà kòkòrò búburú nì tí ó fi ara pamọ́.


