Ní Ȯwȯ Ré Ló Wà Aka Ewi – Ewì Àláwòrán AKA EWIEwì Àláwòrán Ewì-kíkọ dàbí yíya àwòrán pẹ̀lú ọ̀rọ̀. Jẹ́ kí a kọ ewì nípa ọwọ́ wa àti omi. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú oríṣiríṣi ìrísí. Kí ni ohun tí o rí níbí ? Ewì lè máà sọ̀rọ̀ púpọ̀. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Ṣàpèjúwe rẹ̀. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Ó lè ṣàfiwé ènìyàn pẹ̀lú ohunkóhun. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Ṣàpèjúwe rẹ̀! Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! O lè fi ǹkan yìí wé ohun mìíràn. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Copyright Polly Alakija Ṣàpèjúwe rẹ̀. Ní báyìí, ìwọ náà ti di akéwì ! Previous Activity Back to Worksheet Next Activity