ÀWỌN AWὸRAN

Àwọn ayàwὸrán ní gbogbo àgbáyé, láti ibẹ̀rẹ̀ àkόkὸ, ni wọ́n ti máa n ya àwọn ènìyàn..Àwọn ayàwὸrán ti máa ń ya àwọn àwὸrán ẹni ti a jẹ́ àti ohun ti a ńṣe nígbà gbogbo. Ọwọ́ leè sọ àwọn itàn tό lágbára.

Awὸrán wo ní ό jẹ́ ààyό rẹ? Ní báyìí iṣẹ́ kàn ọ́!

Copyright Victor Ekpuk

“All Fingers Are Not Equal ” Victor Ekpuk . Nigeria, 2009.

Copyright Keith Haring

Keith Haring. USA , 1958-1990

Copyright Case Maclaim

Hand Mural

“Under Hand” by CASE . Berlin , 2015

Copyright Lagos State Government , 2016

”Omo Eko ” by Kuramo Primary School, Lagos ,Nigeria  2017.

Copyright Andrew Hall

Rock Art , South Africa. BC 6,000

Copyright Harivansh ,Ibadan 2020.