GBA AWỌN KIKUN JADE
Íhó-ọṣẹ Àti Kòkòrò

Fún ẹgbẹgbẹ̀rún ọdún ni àwọn ènìyàn ti ń ya àwòrán ọwọ́. Nínú àwọn ihò-ilẹ̀ jákèjádò ayé, a óò rí àwọn àwòrán ọwọ́ àdáyébá.

Cueva de las Manos, Argentina.

A sì tún ń gbádùn láti máa ya ọwọ́ ní ọjọ́ òní !

Copyright Polly Alakija

Kó ọ̀dà jáde! Jẹ́ kí a kun àwòrán tí yóò rán wa létí láti fọ ọwọ́ wa pẹ̀lú ọṣẹ púpọ̀ kí ó lè ṣe ìdènà kòkòrò nì. 

O ó nílò:

1. Ọ̀dà olómi mẹ́ta tí aró wọn yàtọ̀ síra wọn.

2.Ìwé pélébé kan. 

3.Gègé ìkọ̀wé àti búrọ̀ṣì