GBA IGE
Ègé Àláràmbarà
O lè ya àwòrán pẹ̀lú àwọ̀ méjì tàbí mẹ́ta péré. O lè fi aṣọ tàbí ewé-ìwé gé oríṣiríṣi ìrísí láti fi ya àwòrán.


Copyright Polly Alakija
Olùyàwòrán àti àgbẹ́gilére faransé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Matisse fẹ́ràn láti máa dárà nípa gígé ewé-ìwé aláwọ̀ sí oríṣiríṣi ìrísí.
O máa nílò:
1. Èwe-ìwé méjì tí àwọ̀ wọn yàtọ̀ síra wọn.
2. Abẹ tàbí àlùmọ́gàjí
3. àbùlẹ̀ (oun tí a fi ń lẹ ǹkan)





Copyright Polly Alakija