JẸ KI A GBA AWỌ
Àwòrán Ọlọ́ Múrálì
Láti fohùn sókè, àwọn ayàwòrán mìíràn á máa yàwòrán olódà sí ibi gbangba.
Tí o bá ń ya àwòrán ọlọ́dà múrálì, ó pọn dandan kí o ṣe ìpinnu ohun tí o fẹ́ kùn.

Dáàbò bo aṣọ rẹ kí o sì gbádùn iṣẹ́ náà !

Àwòrán ọlọ́dà yìí rán àwọn ọmọdé létí láti fọ ọwọ́ wọn ní gbogbo ìgbà tí wọ́n bá lọ ilé ìgbọ̀nsẹ.

Ṣe àtẹ̀jáde àwòrán “Soap Suds and Bugs” kí o sì kùn-ún.
Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é!
Àwòrán ọlọ́dà Ọmọ Èkó ṣàkàwé ohun tí ó lè wà nínú àwọn ìkánsílẹ̀omi kéékèèké.




Copyright Polly Alakija
Ṣe àtẹ̀jáde àwòrán “Ọmọ Èkó ” kí o sì kùn-ún. Kí ni ó wà ní ọwọ́ rẹ?
Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é!