JẸ KI A GBA AWỌ
Gerard Sekoto

Gerard Sekoto (1913-1993) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè South Africa. Ó gbé ní Paris fún ìgbà pípẹ́. Ó sì jẹ́ olùkọ́, ayàwòrán àti akọrin.

Copright "Father and Baby" Gerard Sekoto

Ó fẹ́ràn láti máa ya àwòrán àwọn ọmọ orílẹ̀- èdè rẹ̀.. Ó fẹ́ràn láti máa yàwòrán àwọn ènìyàn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe wà ní ibùgbé wọn, tí  wọ́n sì ń ṣàkóso iṣẹ́ ọ̀jọ́ wọn.

Copyright "Mothers and Children" Gerard Sekoto

 Ọ̀kọ̀̀kan nínú àwọn àwòrán yìí sọ ìtàn nípa ohun tí  àwọn ènìyàn gbé lọ́wọ́

Copyright “Song Of The Pick” Gerard Sekoto

Níhìn-ín ni mẹ́rin nínú àwọn àwòrán re. Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì kùn-ún

Five Cowries

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì kùn-ún!

Five Cowries

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì kùn-ún!

Five Cowries

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì kùn-ún!

Five Cowries

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì kùn-ún!

Copyright Polly Alakija