PADE AKEWI
Donna Ogunaike

.DONNA jẹ́ agbẹjọ́rò ati akéwì. Yíó sì máa fi ọ̀rọ̀ òun orin ran àwọn ènìyan lọ́wọ́láti pa ìtàn-an wọn.
DONNA naa man ko orin.
Ránti pé tí o bà ńfọ ọwọ́ rẹ, ó pọn dandan láti lo ọṣẹ kí o sì fọ ọwọ́ rẹ fún ogún ìsẹ́jú àáyá, ó ké ré jù.
Ṣé o lè kọ ewì tàbí orin nípa ọwọ́-fífọ̀fún ogún ìsẹ́jú-àáyá.
èyí ni ewì tí DONNA kọ fún ọ !

Mo dúpẹ́fún òrùn
Mo dúpẹ́fún eèpè
Mo dúpẹ́fún bí wọ́n ti ń ṣe
Tí wọ́n sì ń padà gẹ́gẹ́ bíi òjò.
Èmi ń yọ nínú ọlá wọn
N ó sì máa fọ aṣọ mi nígbà mìíràn
Omi ọṣẹ ta
ó yọ ọwọ́ ọṣẹ
tí ó péjọ pọ̀ sí ibi ìka mi
ní ọ̀nà yìí
mo ṣe ìmọ́tótó ara mi, mo sì ń ṣeré
Láti dènà kòkòrò àrùn búburú náà.

Nítorí náà, ní ojojúmọ́
N ó gbo gbogbo ohun ìbẹ̀rù kúrò
N ó ta omi, n ó yọ ọwọ ọṣẹ
N kò kánjú
N ó sì fọwọ́ mi mọ́

Bí mo ti ṣe ń fọwọ́ mi, ni mò ń kọrin
nítorí n ò kí ń ṣe àlejò ètò yìí
Ó kéré jù, n ó ṣeé nígbà mẹ́fà lójúmọ́
Ní báyìí, gbo ọwọ rẹ pọ̀
Kí o sì kọrin bí ọṣẹ ṣe ń hó
Kí o sì ṣan kòkòrò búburú náà nù.