JU OHUN GBOGBO SILẸ KI O YA AWORAN
Jẹ́ Kí A Pa Tondó/Àmì Pọ̀
Pablo Picasso jẹ́ gbajúmọ̀ oníṣẹ́ ọnà láti orílẹ̀-èdè Sípéènì. Ó sì féràn láti máa ya ọwọ́tó mú ǹkan dání. Kí ni ìwọ yóò yà pẹ̀lú ọwọ́ rẹ tí ó mú ǹkan dání?

Kini o wa ni ọwọ rẹ Ọgbẹni Picasso ?

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é!
Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é! Ṣe àtẹ̀jáde kí o sì yà-á. Pa àwọn tondó pò kí o sì kun àwòrán náà.