JU OHUN GBOGBO SILẸ KI O YA AWORAN
Jẹ́ Kí A Ya Àwòrán Ọwọ́

 Ṣé o ní gègé -ìkọ̀wé tí ó mú àti ewé-ìwé? Tí o bá ní èyí, o ti ṣe tán láti yàwòrán !

Òfin yíya àwòrán: Kò sí òfin kan ní pàtó.

Jẹ́ kí a ya ọwọ́. Ó ṣòro púpọ̀fún gbogbo ayàwòrán láti ya ọwọ́, ṣùgbọ́n o lè ṣe-é !

Copyright Polly Alakija