JU OHUN GBOGBO SILẸ KI O YA AWORAN
Níhìn-ín Ni Mo Wà

Àrùn COVID-19 súre tàn. Ó ń tàn káàkiri gbogbo àgbáyé. Ó kù sí wa lọ́wọ́láti dènà títànká-a rẹ̀.

Kí ni o rò pé ó jẹ́ atọ́kùn títànká-a rẹ̀

.Ṣe àtẹ́jáde àwòrán ayé. Níbo lo wà? Orúkọ orílẹ̀-èdè mélòó ni o mọ̀? Gbé àṣíya orílẹ̀-èdè rẹ lé àwòrán orílẹ̀-èdè rẹ kí o sì kùn-un. 

Five Cowries

Ṣe àtẹ̀jáde rẹ̀ kí o sì ṣe-é!

Copyright Polly Alakija