SỌ ITÀN RẸ FÚN MI
AA Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Apanílẹ̀rín!

Njẹ́ o mọ ẹníkẹ́ní ti o rán ọ léti àrùn fáirọ́ọ̀si Corona?Ṣé o leè sọ itàn kan fún mi nípa Rona?

Copyright Africa CDC

Gbogbo wa nífẹ̀ẹ́ láti máa gbọ́ itàn. Ní báyìí, àsikὸ tìrẹ ni láti sọ itàn kan. Kìí ṣe gbogbo ígbà lo ní láti máa kọ itàn. O tún leè ya àwὸrán itàn náà. Njẹ́ o leè ya àwὸrán itàn tìrẹ ní ilànà apanílẹ̀rín ti a là silẹ̀ fún ọ?

Renewable Energy

Copyright Polly Alakija

Rántí:

1.   Jẹ́ ki o rọrùn púpọ̀.

2.  Gbogbo àwọn itàn lό máa ńní ẹ̀yà mẹ́ta: ibẹ̀rẹ̀, àarin àti ipari.

3. Àwọn itàn nígbà gbogbo máa ń bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú iṣὸro kan, ti o nílὸ láti yanjú.

4.  Ṣe ẹ̀dá ẹni àkọ́kọ́ itàn bi ìwọ, tàbi bi ẹnikan ti o mọ̀.

5. Lo àwọn ọ̀rọ̀ inú “Odò àwọn èrὸ”.

6.  Ní akikanjú kan!

Five Cowries

Tẹ̀jáde, ki o si lὸÈyi ní diẹ̀ nínú àwọn ilànà itàn apanílẹ̀rín ti o leè tẹ̀ jáde ki o si lὸ